OJU IMO TECH

OJU IMO TECH Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from OJU IMO TECH, Ayetoro-Itele, Ayetoro-Itele.
(1)

E k'aabo si OJU_IMO TECH

A kọ́ ọ bí o ṣe lè lo AI láti ṣiṣẹ́ ọlọ́gbọn, kó owo, àti láti dàgbà ní ayé oni-nọ́mbà.

🎓 AI Tutorials
💼 Make Money with AI
📱 Tools & Tips (ní èdè Yorùbá)

17/06/2026

How To Create ChatGPT Photo Editing (Yorùbá)

Prompt wá ní abala ariwisi wa (Comment sessions) ⬇️


゚viralシ

17/06/2026

I got over 10 reactions on one of my posts last week! Thanks everyone for your support! 🎉

16/06/2026

App ọfẹ́ fún Àwọn Fideo Ai (Free App to generate Ai videos) ⬇️

Nínú ẹ̀kọ́ Ojú-Imọ̀ TECH yìí, màá fi hàn yín app ọ̀fẹ́ kan tí ẹ lè lò láti ṣe AI videos tó dára gan-an.

Ẹ má gbagbe láti tẹ Like, Share àti Follow.

Bí a bá ní ibere, e tẹ sì abala ariwisi wa ti nse Comments section



Kí ni AI ní èdè Yorùbá?AI túmọ̀ sí Artificial Intelligence, èyí tí a lè pè ní Ọgbọ́n Apinlẹ̀rọ ní èdè Yorùbá.Ọgbọ́n Apin...
08/06/2026

Kí ni AI ní èdè Yorùbá?

AI túmọ̀ sí Artificial Intelligence, èyí tí a lè pè ní Ọgbọ́n Apinlẹ̀rọ ní èdè Yorùbá.

Ọgbọ́n Apinlẹ̀rọ ni agbára tí a fi ń kọ́ ẹ̀rọ tàbí kọ̀ǹpútà láti ronú, kọ́ ẹ̀kọ́, dáhùn ìbéèrè, ṣe ìtúpalẹ̀, kọ ìwé, dá àwòrán, ṣe fidio, àti ràn ènìyàn lọ́wọ́ bí ẹni pé ó ní ọgbọ́n ènìyàn.

Ní ṣókí:

AI ni Ọgbọ́n Apinlẹ̀rọ tó ń jẹ́ kí kọ̀ǹpútà lè ṣe àwọn iṣẹ́ tí ó sábà máa ń fẹ́ ìmòye ènìyàn.

Example:
ChatGPT, Google Translate, AI image generator, voice assistants, and recommendation systems are all examples of AI.

Ní OJU IMO TECH, a ń kọ́ AI ní èdè Yorùbá kí ìmọ̀ ẹ̀rọ lè rọrùn fún gbogbo ènìyàn.

Àdúrà fún Ọ̀sẹ̀ Tuntun Ìbẹ̀rẹ̀ oṣe yí yóò jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ ayọ̀ fún ọ. (The start of this week will be the start of joy for y...
08/06/2026

Àdúrà fún Ọ̀sẹ̀ Tuntun

Ìbẹ̀rẹ̀ oṣe yí yóò jẹ́ ìbẹ̀rẹ̀ ayọ̀ fún ọ. (The start of this week will be the start of joy for you.)



゚viralシ

31/05/2026

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Bipin Bipin, Princess Olatokunbo Adedapo, Ajay Dewangan, ...
29/05/2026

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Bipin Bipin, Princess Olatokunbo Adedapo, Ajay Dewangan, Unice Adeola, Lý Nguyệt, Febby Mbangweta, Brayo Mmoja

28/05/2026

Mo yi àwòrán mi padà sí hand-drawn sketchbook character sheet that tells my story (to nsọ ìtàn mi àti ìṣe mi)

Want the exact prompt I used? 👀

Comment “PROMPT” má sì ṣe Video lè lórí pelu Prompt (àte ranse)

28/05/2026

゚viralシ

28/05/2026

AI kii ṣe magic 😮🔥
Correct prompt + creativity ni secret! Mo ṣẹda professional passport picture pẹlu AI within minutes.

Follow Ojú-Ìmọ̀ TECH for more AI tricks

Ẹ join kiláàsì fún eko púpọ̀





゚viralシ

Address

Ayetoro-Itele
Ayetoro-Itele
112101

Telephone

+2348140110054

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when OJU IMO TECH posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share