06/09/2022
Today is Tuesday
Ti awon yoruba pe ni ojo isegun
Bi oluwa tin be ,ti emi awon woli sin be pelu ,oluwa kio fun oo ni isegun lati orun ,
Gbogbo ajadi apere ti aye gbele ee ,lowo
Oluwa fi na joo danu