OJU IMO TECH

OJU IMO TECH Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from OJU IMO TECH, Ayetoro-Itele, Ayetoro-Itele.
(1)

E k'aabo si OJU_IMO TECH

A kọ́ ọ bí o ṣe lè lo AI láti ṣiṣẹ́ ọlọ́gbọn, kó owo, àti láti dàgbà ní ayé oni-nọ́mbà.

🎓 AI Tutorials
💼 Make Money with AI
📱 Tools & Tips (ní èdè Yorùbá)

02/08/2026

Aku isinmi òní oooo

Ẹ kú Oṣù Tuntun!💖💖💃💃🌹🌹 Kí oṣù yìí mú ìbùkún, àlàáfíà, ayọ̀ àti ìlọsíwájú bá ọ. Gbogbo ohun rere tí o ń retí yóò ṣẹ ní or...
01/08/2026

Ẹ kú Oṣù Tuntun!💖💖💃💃🌹🌹

Kí oṣù yìí mú ìbùkún, àlàáfíà, ayọ̀ àti ìlọsíwájú bá ọ. Gbogbo ohun rere tí o ń retí yóò ṣẹ ní orúkọ Ọlọ́run.

Ẹ káàbọ̀ sí oṣù tuntun!



🤖 AI Kò Nira! AI Is Not Difficult.Imagine learning ChatGPT and other AI tools in simple Yoruba and English.No tech backg...
25/07/2026

🤖 AI Kò Nira! AI Is Not Difficult.
Imagine learning ChatGPT and other AI tools in simple Yoruba and English.

No tech background needed. No confusing grammar. Just practical lessons you can use immediately.

Follow Ojú-Imo TECH and join our upcoming AI class.

📩 Comment "AI" or click the link on CS to join our WhatsApp group

OJU IMO TECH

🤖 AI Kò Nira! AI Is Not Difficult.Still confused about AI? This beginner-friendly eBook explains AI in simple Yorùbá + E...
24/07/2026

🤖 AI Kò Nira! AI Is Not Difficult.

Still confused about AI? This beginner-friendly eBook explains AI in simple Yorùbá + English no tech background required.

✅ Learn ChatGPT & other AI tools
✅ Use AI for business, work, and daily tasks
✅ Easy step-by-step guide

📖 Start your AI journey today.

👉 Click the Selar link on the comment session to get your copy now!

Ẹ fi ojú s'ona fún video wá laipe
20/07/2026

Ẹ fi ojú s'ona fún video wá laipe


Ẹ jeki a múra sílẹ̀ fún kiláàsì wa lálẹ́ yìí ní aago 8:00pm.Bí ẹ bá fẹ́ kí kiláàsì náà máa lọ síwájú:✅ React sí ìfìwérán...
19/07/2026

Ẹ jeki a múra sílẹ̀ fún

kiláàsì wa lálẹ́ yìí ní aago 8:00pm.

Bí ẹ bá fẹ́ kí kiláàsì náà máa lọ síwájú:

✅ React sí ìfìwéránṣẹ́ yìí.
✅ Fi "Mo wà níbẹ̀" sílẹ̀ nínú comment.
✅ Wà lórí WhatsApp ní 8:00pm.

A fẹ́ kọ́ àwọn tó ti ṣetán láti kọ́.

Link sì WhatsApp wá ní abala ariwisi wa (Comment sessions) ⬇️

Ojú-Ìmọ̀ TECH
Ìmọ̀, Ẹ̀kọ́, Àṣeyọrí.

゚viralシ

Láti darapo mọ wá ní gbogbo òjò àìkú!Ẹ tẹ ìlà pọ (Link) ni abala ariwisi wa ti nse Comments section ⬇️⬇️⬇️
16/07/2026

Láti darapo mọ wá ní gbogbo òjò àìkú!

Ẹ tẹ ìlà pọ (Link) ni abala ariwisi wa ti nse Comments section ⬇️⬇️⬇️



Ṣé o fẹ́ kí iṣẹ́ rẹ, owó oṣù rẹ àti ẹ̀kọ́ rẹ yára gòkè?These are the AI tools every beginner (àwọn alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀) shoul...
16/07/2026

Ṣé o fẹ́ kí iṣẹ́ rẹ, owó oṣù rẹ àti ẹ̀kọ́ rẹ yára gòkè?

These are the AI tools every beginner (àwọn alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀) should start using today!

1. 🤖 ChatGPT – Fún writing, ideas, research àti coding.

2. ✍🏽 Google Gemini – Fún answers, brainstorming àti Google integration.

3. 🧠 Claude AI – Fún reading long documents, writing àti analysis.

4. 🎨 Canva AI – Fún flyers, presentations, logos àti social media designs.

5. 🖼️ Microsoft Designer – Fún creating stunning graphics instantly.

6. 🎥 Google Flow AI – Fún Image-to-Video àti AI video creation.

7. 🎬 CapCut AI – Fún editing videos, auto captions àti AI effects.

8. 🗣️ ElevenLabs – Fún realistic AI voice-over.

9. 🌍 Google Translate AI – Fún translation sí Yorùbá, English àti èdè míì.

10. 📑 NotebookLM – Fún studying, summarizing notes àti learning faster.

💡 Ojú-Ìmọ̀ TECH: A nkọ́ AI ní èdè Yorùbá, láti ìpele alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ dé ọjọ́gbọn.

👉 Follow Ojú-Ìmọ̀ TECH for more AI tutorials in Yorùbá & English.

Majonagbe Fausat Omobolaji

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Awoyomi James, Usman Yakubu Danboka, Discovery Chanel
16/07/2026

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Awoyomi James, Usman Yakubu Danboka, Discovery Chanel

Address

Ayetoro-Itele
Ayetoro-Itele
112101

Telephone

+2348140110054

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when OJU IMO TECH posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share