Emmayo Services

Emmayo Services Car sales, diagnosis and repairs Automobile
Real Estate
Communications

We have presence in Lagos, Port Harcourt and Abuja

24/05/2026

SAMUẸLI KEJI 22:4
[4]Emi o kepe Oluwa, ti o yẹ lati ma yìn: a o si gbà mi lọwọ awọn ọta mi.

I will call on the LORD, who is worthy to be praised: so shall I be saved from mine enemies.

17/05/2026

JOHANU 9:38
[38]O si wipe, Oluwa, mo gbagbọ́, o si wolẹ fun u.

And he said, Lord, I believe. And he worshipped him.

10/05/2026

SAMUẸLI KEJI 6:11
[11]Apoti-ẹri Oluwa si gbe ni ile Obedi-Edomu ara Gati li oṣu mẹta: Oluwa si bukún fun Obedi-Edomu, ati gbogbo ile rẹ̀.

And the ark of the LORD continued in the house of Obededom the Gittite three months: and the LORD blessed Obededom, and all his household.

03/05/2026

ORIN DAFIDI 73:26
[26]Ẹran-ara mi ati aiya mi di ãrẹ̀ tan: ṣugbọn Ọlọrun ni apata aiya mi, ati ipin mi lailai.

My flesh and my heart faileth: but God is the strength of my heart, and my portion for ever.

01/05/2026
28/04/2026

Address

Port Harcourt

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Emmayo Services posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Business

Send a message to Emmayo Services:

Share